《Ariwo Ayo》歌词

歌手: 张妮 / Lurjay
歌词字数:1,128 歌词行数:34 当前语言:中文 时间轴歌词:— 歌词翻译:—
📄 纯文本

Aríwo ayó, ni'le wà, ó (àmin oh)

Kan'pàriwo ayó, ni isė wà, ó (àmin oh)

Aríwo ayò, lė'bi wà, ó (àmin oh)

Kan'pàriwo ayó, ni'le wà, ó (àmin oh)

Oh'Lord of mercy, (yė-éh-yė)

Jah bless our way, (há-hà-hà-hà)

È'gbéwà, ti'nkō ile, båbå sè ti'wá ní iròrún, ó (ãsė)

It not easy but íwó ni helper (helper)

Bless us with unlimited rábá (rábá)

Kan'pàriwo, pe ibo'ni àgbe, gbà

Ota n'binu (yeah), ota n'pe-ègan

Mu ire'wa, ki á'le fi'wõn pí ìtan

Ki fans rí wà, kan'sòwipè à'damõ

If no be anything, kí álubàrikà má pò

Aríwo ayó, ni'le wà, ó (àmin oh)

Kan'pàriwo ayó, ni isė wà, ó (àmin oh)

Aríwo ayò, lė'bi wà, ó (àmin oh)

Kan'pàriwo ayó, ni'le wà, ó (àmin oh)

Ìkan tí mà ję, ni mo'wà kírì

Ki má sė pàdé, o'hun to mà jé mi

Tà'bá n'sísė, kà mà jėrė

Ká mà sę rí, ogun kosí kosí

Gbogbo ò jó, íbí tì bá dė loní (o) àyõ nì ko jė tęmí

As i dey work, i dey pray (o) owo ní kí won'mà fí wà mí rí

(Àyó), àyó õ (àyó ní mo tõ rõ)

(Àyó), àyó õ '(àyó)' (àyó ní mo tõ rõ)

Båbå gbó, àwà ómò rė dė

Làtí gbe o'hun èbè wá so'ke sí o

Gėgė bí o tí gbò, ádùrá Elijah

Båbå gbó, àdúrà wà

Aríwo ayó, ni'le wà, ó (àmin oh)

Kan'pàriwo ayó, ni isė wà, ó (àmin oh)

Aríwo ayò, lė'bi wà, ó (àmin oh)

Kan'pàriwo ayó, ni'le wà, ó (àmin oh)

🎧 猜你喜欢

共 7 首

🎲 随机歌词

共 8 首